*IDIJE ₦20,000 CASH* Jẹ ẹbun ₦20,000 nipa fi fi bi o - TopicsExpress



          

*IDIJE ₦20,000 CASH* Jẹ ẹbun ₦20,000 nipa fi fi bi o ṣe fẹran Ọba-orin Saheed Osupa Akorede han. Ẹnikẹni toba ṣetan lati dije gbọdọ ṣe afihan ara rẹ lori aworan video ti a fi ẹrọ alagbeka(HANDSET) ṣe fun okere tan iṣẹju mẹta. Lati peregede fun idije yi, o gbọdọ ṣe awọn nkan wọn yii ninu aworan video ti o fẹ fi ranṣẹ: 1. Sọ orukọ ara rẹ ati ibi ti o n gbe (fun apẹrẹ; Eko, Abeokuta, Dubai, Kano, Korea, Finland, Garbon ...abbl. 2. Sọ idi ti o fi fẹran OSUPA (KSO). 3. Fi awo-orin(RECORD) meji pere han ninu awọn awo-orin KSO ti o ni (VCD tabi audio CD). 4. Kọ eyikeyi ninu orin KSO, fun apẹrẹ ori lo n baniṣe ibaṣepe eniyan a ti ruju tipẹ ....abbl. 5. Ṣe adura alekun orire fun KSO ni idi iṣẹ orin. Fi aworan video yi ranṣẹ si ọkan ninu awọn group meji yi; OLUFIMO FANS CLUB OF FINLAND tabi FRIENDS AND FANS OF KING SAHEED OSUPA. Anfani lati fi aworan video tirẹ ranṣẹ ma wa si opin ni ọjọ Sunday 17/8/14. Awọn ti wọn ba fi aworan video arawọn ranṣẹ tiwọnsi tun ṣe ikan toyẹ kanṣe ninu aworan yẹn nikan nama ni anfani lati kopa fun idije ₦20,000 CASH yi. Fi ifẹ ti oni si KSO han. Olufimo titi ayeraye, Osupa ni igbagbo. .... Ọrọ yi wa lati ọwọ Olufimo Gbogbo Finland (FOWOSERE OF OLUFIMO FB) ti emi Yusuf Ogunremi (AMULUDUN OF OLUFIMO FB) si ṣe ayan ogbufọ rẹ ni ede abinibi.
Posted on: Fri, 08 Aug 2014 06:43:43 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015