AARUN JEJERE OMU APA KEJI (N TE SIWAJU): Ninu Atejade aarun - TopicsExpress



          

AARUN JEJERE OMU APA KEJI (N TE SIWAJU): Ninu Atejade aarun jejere omu Apa Keji Ti e ka tan yin awon afikun irufe awon eeyan ti aarun yi le yo lenu tabi awon oun to le se okunfa aarun yi: Ojo Ori (A )a ma se Okunfa Aarun Jejere Omu, aarun yii le yo Odomobirin lenu ti kii se dandan ki onitohun je Agbalagba. Aarun jejere omu wopo laarin obirin. Aarun Jejere Omu le yo awon Obinrin to ba Yagan lenu (Infertile Women), Oseere ki Aarun yii yo awon Obinrin ti o ba tete bere Nkan Osu won(early women menstrual period) Aarun Jejere Omu le yo awon obinrin ti o ye ki Nkan Osu won ti pari (Menopause Period),ti won si nse Nkan Osu won lo. Oseese ki Aarun yi yo awon Obinrin ti won kundun lati ma je Oun Jije ti oni Ora (Fat Foods), Epa {ground- nuts), epa kaj(cashew nuts), eran, eja ati obe ti wo se wa sinu agolo ( processed meat/fish & canned soup). Fun Itoju to peye nipa Aarun Jejere Omu ekan si Dr Sholaja Solanke Oluwatoyin ni no 5 Samson Okeyemi Abule Ijoko Lemode tabi ki e pe No yi 08065860161
Posted on: Fri, 13 Sep 2013 10:57:28 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015