ARUN IKO (APA 3), Bi ati se nba idanileko wa lo lose to loja, mo - TopicsExpress



          

ARUN IKO (APA 3), Bi ati se nba idanileko wa lo lose to loja, mo menuba bi ase le mo irufe aarun ti ole se okunfa aarun iko, a ma bami kalo lose yi; Nje Aarun Iko A Ma Ran E lomiran: Aarun iko a ma tete ran elo- miran. Irufe Awon Eeyan Wo Lo Le Ni Aarun Iko:Iko a ma mu omode ati agbalagba . Asiko Wo Ni AarunIko Ma Nja: Ko si asiko kan ni pato sugbon aarun yi a ma wopo lasiko ojo (rainning season). Kinni Ona Abayo Fun Eniti Oba Ni Iko Ti Ko Le Ri Kelebe Ofun Re Tu: Ki se dandan lati lo ogun fun iko yi, sugbon a ni la loawon nkan ti a le fi de iko yi ki aba le ma ri kelebe yi tu. Bi A Se Toju Aarun Iko: Lakoko se itoju aarun ti o ba se okun fa iko tire, nidakeji eniti o ba ni iko ki o ma mu omi gbigbona eyi yara sise lara ju ogun miran lo. Ona miran ti a fi le se itoju aarun iko ni ki a fi (menthol) sinu omitoba gbona ki a fi aso bori mo omi yi, ki asi ma fa ooru gbigbo na yii simu fun iseju meedogun si ogun iseju (e te siwaju lati le pari apa keta)
Posted on: Fri, 30 Aug 2013 06:49:02 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015