AWON KOKO INU IWE IROYIN ILE WA TO JADE LONI. (Wedsday, - TopicsExpress



          

AWON KOKO INU IWE IROYIN ILE WA TO JADE LONI. (Wedsday, 6/8/2014). • Egbe oselu APC seleri lati wako pelu ijoba bi ibo odun 2015 bani magomago ninu - The Guardian. • Oko ofurufu ile Amerika ti nwa awon omobinrin ti o wa lakolo awon boko haram ni apa Ariwa ile wa - This Day. • NMA: O fe dabi eni pe matironu(matron) ile iwosan kan ti ni arun Ebola lara - Compass. • Awon gomina Guusu si Guusu(South-South) ati agbagba egbe oselu PDP fi onte lu Jonathan lati tun gbe apoti idibo fun odun 2015 - The Nation. • Idi ti awon Osun o gbodo dibo fun PDP, Omooba Olagunsoye Oyinlola lo so bee lana - Tribune. • Gomina Amaechi: Orile-ede Niajiria wa ninu ewu nla o - Punch. • Kiko esi awon oluwadi lori oro Al-Makura lewu pupo, Falana lo so bee - Daily Independent. • Awon odo egbe oselu PDP sun kaadi omo egbe ni ipinle Rivers - Punch. • Awon agbebon pa eyan mejo ni Port Harcourt - The Nation. • Owo te eyan kan to nsowo awon obinrin lati ilu kan si omiran ni Calabar - The Sun. • Won bura fun igbimo eleni meje lati wadi igbakeji gomina ipinle Enugu lori sise owo mokumoku - The Guardian. • Chibok: O ti su wa o, e ko awon omo wa jade, awon to nfi ehonu(protesters) han lo so bee - The Nation. ERE IDARAYA. • FIFA U-20 Women’s World Cup: Falconets ti setan lati wako pelu egbe agbabolu lati orile-ede Mexico - Tribune. • Egbe agbaboolu Lazio ti setan lati san #215m lodun kan fun Onazi lati le darapo mo won - The Nation. • Angola, Eq.Guinea, Gabon fe gba Stephen Keshi gege bi akonimogba - Complete Sport. • Nantes fe ki Oduamadi darapo mo egbe agbabolu won - Complete Sport. Too! Ao ni ri ju bayi lo fun toni, titi ti ao tun fi pade lowuro ola, emi Oludare omo Dipeolu oniroyin yin lo ngba ladura pe aridunnu wa koni dibaje o. Amin. Oodigba! IBORUBOYE O!
Posted on: Wed, 06 Aug 2014 10:50:43 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015