Aheso oro nile aye tawa otidaye ona tinji Afeni toluwa bakoyo - TopicsExpress



          

Aheso oro nile aye tawa otidaye ona tinji Afeni toluwa bakoyo loyo ninu ewu lowo iji omo araye Ilu oyinbo timolo wonloye latilo sinmi Nimofilo funara nisinmi Lawon kan badorie kodo won ni moseso Awonkan ni mogbe lukudi mi Awonkan sope motiku Openifeledumare iyin foba mimo openifun gbogbo eniyan eyin tenfetiwa Enitoko letter ranse, ateni tote waya ranse LatOgun state latabeolumo ojojumo lonko letter ranse, wonte waya ranse ABaNIJE eniyan tonbayanje kiri lojo teba dekun atibanije lao baoje O Ema bawaje O enire kin benire je 2x Tebabawaje oba oluwa asitunwase:: enira kin benire je Awon alaida koluwa yinwon lokan pada:: enire kin benire je Awon elero buburu koluwa yiwon lokan pada :: enire kin benireje Aye ema bawaje o enire kinbenire je Fela omo anikulapo nigba tolo sa merica tolofere dawon laraya beni wonse sosi won ni wonfi sogba ewon Won ni wofi sile tubu haaa ironla lojasi Aruna ishola nko wonni wonfisi detention Haa iro nla lojasi Wontun ni Sunny siwere ha ironla lojasi Chief Obey commander eni olorunda ose farawe nigbatalosi london beni wonseso Wonlakogbo sinu irinse Wontunfi tigbo sile otundi ti LUKUDI Nibolegbetiri lukudi ewi kingbo BABU LUKUDI haah babu lukudi Kosi lukudi rara o:: babu lukudi Ore ofe eledumareni babu lukudi.
Posted on: Fri, 08 Aug 2014 12:33:23 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015