Aku ojumo ninu ile yi mosi tun ki wa ku osu titun ibanuje towa - TopicsExpress



          

Aku ojumo ninu ile yi mosi tun ki wa ku osu titun ibanuje towa nibe koni kan wa,oko ayewa yio gunle si ebute ayo Imaran mi siwa,,,,,,, kise gbogbo eniti nse rere ni eñiyan rere kisise gbogbo eniti nse buburu ni eniyan buruku,eniti kowulo fun o loni olewulo bodi ola kise gbogbo awan ti wan nba oja ni ota re, oseese ki olore re kowa larin wan Ore mi dami emina yio da ore mi yoruba sope odale di pupo nigbati ore re mu inu re dun kosi enikan to gbo sugbon nikete ti ija waye larin iwo ati ore re odi eniyan buruku, Bi ore re kan basubu gbe dide boya ohun ni ahungeli re lola.
Posted on: Fri, 01 Nov 2013 04:37:58 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015