ITANSAN ASA ATI ISE (RAYS OF CUSTOM AND TRADITION), Abala yi - TopicsExpress



          

ITANSAN ASA ATI ISE (RAYS OF CUSTOM AND TRADITION), Abala yi ni a o ti ma fi Asa ati Ise Yoruba Han............... Lara Asa Ati Ise ni IKINI ni ILE YORUBA. IKINI JE OHUN PATAKI FUN IRAN YORUBA, BEE IKINI JE OHUN TI O MU IRAN YORUBA GBAYI JU AWON EYA YOKU LO LAGBAYE, OJULOWO OMO YORUBA GBODO MO BI WON SE NKINI, OMO YORUBA TOBA SAFEKU IKINI KII SE OJULOWO OMO YORUBA, NITORIPE IKINI MA N JE KA MO BI A SE NBOWO FUN ARAWA ATI FUN AGBA, ATI BI A SE LE PON ARA WA ATI ALEJO LE. SUGBON GEGE BI A SE MO, ORISIRISI IKINI NI O WA NI ILE YORUBA. FUN APERE: BI A SE NKI ARA WA NI OWURO, OSAN ATI NI ALE. BI A SE NKINI NI AWUJO PUPO BI A SE NKI OLOMO. BI A SE NKI ONIYAWO BI A SE NKI ONISE OWO LORISIRISI( AGBE, ALAGBEDE, ONIDIRI, ONISE ONA ATI B B L.) BI A SE NKI WON NIBI OKU BI A SE NKI WON NIBI ISILE BI A SE NKI ARA WA NI ASIKO OJO, ERUN ATI ASIKO ODUN. BI A SE NKI ONILE ATI ALEJO……ABBL. NIBAYI EYI TI A MA GBEYEWO NI BI A SE NKI ARAWA NI OWURO, OSAN, ALE, NI AWUJO ATI NIBI OLOMO NI ILE YORUBA. NI ILE YORUBA IDOBALE NI OKUNRIN GBODO KI AGBALAGBA TI OBINRIN NA SI MA KUNLE KI AGBALAGBA. 1)TI O BA SE OWURO –E KU OWURO, E KU OJUMO-- OJUMO IREE(IDAHUN), AJII BII OO -- AJI DADA(IDAHUN) TI O BA SE OSAN –E KU OSAN, E KU IYALETA TI O BA SE IROLE – E KU IROLE, E KU OJORO, E KU ASALE TI O BA SE ALE – E KU ALE, TI O BA SE OBA – KABIYESI O TI O BA SE OLOYE – K’ARA O LE BABA TI O BA SE AREMO OBA—DANSAKI O 2)IKINI NI AWUJO PUPO E KU IJOKO OO--- E MA WO’LE OO(IDAHUN) AJO O TU O--- ENITI YO TU KO NI WO OO(IDAHUN) 3) IKINI NIBI OLOMO. E KU OWO LO’MI O…… ELEDEMARE YO KA KU ARA WA O. A JE OLORUKO PE O TABI A TO OLORUKO OO (TI WON BA TI SO NI ORUKO) SUGBON GEGE BI A SEMO PE EDE YORUBA PIN SI ORISIRISI NIPA IBI-ISENUPE TABI OHUN ILU KOKAN TI A MO SI EDE ADUGBO FUN APEERE….. NI ILU OWO NI IPINLE ONDO, WON MA NKI ARA WON NI OWURO BAYI ………………………… IYEMI, LAAYE OOO (TI O BA SE OBINRIN) IBAMI, LAAYE OOO (TI O BA SE OKUNRIN ) NI EDE AWORI, WON A NI—EEMO OO (E KU OJUMO OO E JOWO A FE KI ONIKALUKU WA JE KI A MO BI A SE NKI ARA WA NI EDE ILU YIN, KI E BAWA FI EDE ILU YIN KI WA NI OWURO, OSAN, ALE, AWUJO ATI NI IBI OLOMO. OYA E JE KI A GBOYIN, KI A KO ARA WA NI EDE, ASA ATI ISE ILE-YORUBA, E YIN OJOGBON GBAGEDE ASA LAWAAAAAA…………
Posted on: Fri, 08 Nov 2013 08:20:21 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015