Iwa rere leso eniyan Teti ki o gbo, ore mi, Iwa rere - TopicsExpress



          

Iwa rere leso eniyan Teti ki o gbo, ore mi, Iwa rere leso eniyan. Bi a bi o ni ile ola, Bi o si fa wara oro mu dagba Bi o ko eko akodori, Bi o reni ba o wa ise rere, A gbo pe o pe na, iwa yi nko? Se iwa rere leso eniyan. Iwa lo n muni i wu eda laye Ola leso ode fun ni. Iwa lewa omo eniyan. Bi o si ri omo eniyan pataki, Ti o n se faari obi to ni, To n fonnu polowo lo boun, Dakun teti gbo mi daradara, Biwa ko si obi ko jamo rara, Ise rere eni lo n gbe ni i ga. Kotesi ofu J.F Odunjo Good Character makes a man Listen my friend, Good character makes a man, If you were born with silver spoon in your mouth, fed with milk or riches, well educated, secure good employment, agreed youre well to do, what about character? Good character they say makes man. Good character makes you, Riches only decorates your outlook. Character beautify you. When you see a well to do person, being proud of his rich parents, listen to me carefully, Charity begins at home, Good character makes you. Courtesy of J.F Odunjo
Posted on: Tue, 29 Jul 2014 10:06:07 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015