Ki gbogbo Alagbara ninu iran re maa teriba fun O lati oni lo. Ki - TopicsExpress



          

Ki gbogbo Alagbara ninu iran re maa teriba fun O lati oni lo. Ki gbogbo eniyan maa yo mo O nibi gbogbo ti O ba de ninu aye. Ala(boundary) ti Onibode idile yin kii jeki Omo Ologo ki o de, loni yi ni Olorun yio gbe O koja re. Orin ayo ti enikeni o tii ko ri ninu iran re, yio ti odo re bere ni Oluwa wi nipa re lowuro yi. Nitorinaa, lo, maa se rere. Ki eri re ki o farahan kiakia ni oruko Jesu Amin. JESU MBO LAIPE O.
Posted on: Fri, 26 Jul 2013 04:36:34 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015