Mo ranti orin kan ta funmi lore ofe lati compose. Orin na lobayi. - TopicsExpress



          

Mo ranti orin kan ta funmi lore ofe lati compose. Orin na lobayi. Modupe temi mosope temi. Mosan jelo miran lo. Modupe temi. Vocal 1. idi timofisope emi san jelo miran lo ni wipe. Mi oo toroje. Beni mi oo loju ekun. Won oo dawo ejo nitori mi. Won oo foku mi ranse sile. Mosan jelo miran lo. Modupe temi. Iwo okan togbo mi. Oye. Komo bose fope folorun. Mogba ladura pe fun iwo tobari amin se. Enu ope re oni kan.
Posted on: Sat, 22 Jun 2013 09:20:53 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015