Ni Oruko Jesu, iwo tio ni anfani lati wonu osu yi laini idiwo ati - TopicsExpress



          

Ni Oruko Jesu, iwo tio ni anfani lati wonu osu yi laini idiwo ati idena, bi ere bi awada imo ota koni se leo lori, kio tojade ninu odun yi, ni gbogbo ibi tie ni nni anfani lati maka adura, tie pa owore mejeji po kio si samin adura yi, ojo die loku ki odun yi pari, Emi re pelu awon omo re Ati Temi ni yio pari e, bi onsenjade lo lowuro yi, lati wa onti ooje lo,oorun ti yi o-jade loni kio tiwo alaanu re yio wao ri, iwo ti aye fisinu igbekun iwo ti aye da duro, iwo ti aye ti paro ogo re ati iwo ti ise re nbe ni Egypt bi ti awon omo isreal tion seru iseda miran, kini anpe ni Egypt, ile igbekun ni, ile ide, ile aini isinmi, ile airise ni, bibeli sope nipa woli kan ni amu isreal jade kuro ni Egypt, emi ni Oluwa ran sio lowuro yi bia se ran Mose si awon omo isreal, bio o bale se amin ni gbogbo ibi ti ontinka adura yi, ninu igbekun tio wa, ti aye re kotesiwaju, mosoro jade gege bi WOLI Olorun alaaye, Emi-mimo tie wonu ogo ayeiraye re lo, waabo ninu ogun, ki odun yi to pari oorerin Ayo, ni Oruko Jesu Oluwa Ati Olugbala Wa Amin,,
Posted on: Thu, 05 Dec 2013 05:16:21 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015