OGEDE NIGERIA N BA JE A SO WIPE SE LO N PON, EGBO EYIN ENIYAN MI, - TopicsExpress



          

OGEDE NIGERIA N BA JE A SO WIPE SE LO N PON, EGBO EYIN ENIYAN MI, SE OHUN TI O TO NI, ALAGA AJO OKO OFURUFU NI ORILE EDE YII SE, TI O LO FI EGBELEGBE MILLIONU NAIRA RA OKO AYOKELE, NIBI TI AWON KAN KO TI LE RI OHUNJE OJO JE LORILE EDE YII, TI AJO ASSU NAA YARI FUN IJOBA APAPO PE O DI IGBA TI WON BA SANWO KAWON TO WOLE, SE ELEYII TONA BI? EGBO ORO AWON BOKO - HARAM YII NAA TUN N PE LEKE SII LOJO JUMO DEBI PE, WON TUN LO N WON ASO SOJA LATI SE AWON AGUBANIRO NI JAMBA, LORILE EDE YII NAA NI, SE TI AWON AJINIGBE NI KA SO NI IYEN TUN KA MAMA, LORI GBOGBO E NAA IJOBA KO RI NKAN SE SI, AFI IPADABO LEKEJI LO KA GBOGBO WON LARA NAIJA IBA BAJE KODA KODARU TI WON BA TI RI OWO KO ABUSEBUSE, SUGBON E RANTI PE AKOGILEPA TI IGBEYIN LOJU. KOSI ISE FUN AWON ODO LANGBA WA. BI WON BA, BA LO TI WON BA BO WON A NI GBOGBO WA NI IJOBA BE IRO TO JINA PATA SI OTO NI, SE ENI TI KO RI OSAN ILE DEBI ORU OKO LONI IJOBA NI TABI ENI TI GBOGBO IDILE E RI SE TI WON TUN RI JE LONI IJOBA, SUGBON MOMOPE LOJO KAN LAMA BO LOKO AWON AFEAJE MA FE AYO TI N FUNNI LOKO IDI OPE RO, EJE KI GBOBGO WA TEWO ADURA PE, OLORUN KONI JE KI WON FI EJE TEMITIRE SETUTU ORILE EDE YII.
Posted on: Sun, 20 Oct 2013 02:27:55 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015