ORO AGBA(Wise Word): Huum...lotito,opo oro a maa niro ninu,sugbon - TopicsExpress



          

ORO AGBA(Wise Word): Huum...lotito,opo oro a maa niro ninu,sugbon ki tun ni anfaani oro belenja ti a so,eyi ti ko ni koko kankan ninu bo ti wu ko mo?. Ki gbogbo soro-soro o maa soro so nitori bi ogiri se leti oro to, eni ba wa sun mo lo lee mo oun togiri ngbo!!. A ku ijosin toni o. Oluwa Yio gbadura wa. Ojumo re eyin temi!!. Translation: Huum...truly too much spoken words have iota of falsehood but then whats the benefit inherent in short spoken words that have no meaning whatsoever?. Let every speaker be conscious of his listeners because as much as wall has ears, its someone thats closer to it that can decode what it captures. Happy worship of today. May God accept our prayers!!. Good morning my people!!.
Posted on: Sun, 07 Sep 2014 07:26:48 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015