Ohun Oluwa,E fi fun Oluwa,eyin omo awon alagbara,e fi ogo ati - TopicsExpress



          

Ohun Oluwa,E fi fun Oluwa,eyin omo awon alagbara,e fi ogo ati agbara fun oluwa.ohun Oluwa nbe lori omi pupo,Olorun nsan ara,ohun Oluwa nfa igi kedari ya,loto Oluwa nfa igi kedari ya,on ya owo ina,on mi agiju,o mu abo agbonrin bi,on fi igbo didi han,ninu tempili re lan soro ogo re,o joko lori isan omo,nitoto Oluwa joko bi Oba laelae,Oluwa yo fi agbara fun awon eniyan re,Oluwa yo fi alafia busi fun awon eniyan re.ps 29
Posted on: Fri, 06 Sep 2013 00:22:54 +0000

Trending Topics




© 2015