Ohunkohun ti a ba de ni aye, beeni a o si de ni orun pelu. - TopicsExpress



          

Ohunkohun ti a ba de ni aye, beeni a o si de ni orun pelu. Nitorina mo pase sinu aye re loni, ohunkohun towu tole je, ti o ti baje, daru,dojuru ninu aye re, ninu eya ara re, ninu ise re, isowo re, ninu eko re, nibi oja tabi ibise re,ninu igbeyawo re, ebi re ati ile re. Ki agbara Olorun, ore ofe Olorun, aanu ati iyanu nla olorun ki o wa o ri, ki o ra o pada, ki o segun fun o, tun aye re ati gbogbo ona re se bi o ti nse amin ko amin si adura lowolowo yii. Whatever is bound on earth shall be bound inheaven. Therefore, I decree upon ur life today,that whatsoever that has or might have damaged or destroyed in your life, in your body, in your skills, your carrier, your academics, your business, your marriage, your home, your family MAY THE POWER, FAVOUR, MERCY, GRACE AND MIRACLE OF GOD LOCATE YOU AS YOU SAY AND TYPE "AMEN" TO THIS PRAYER TO REPAIR, DELIVER YOU, YOUR LIFE AND EVERYTHING.
Posted on: Wed, 17 Jul 2013 05:16:53 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015