They say: We are obedient, but when they leave you ( Muhammad S A W ), a section of them spend all night in planning other than what you say. But Allah records their nightly plots. So turn aside from them (do not punish them ), and put your trust in Allah. And Allah is Ever All-Sufficient as a Disposer of affairs. ※ Won wipe: Itele (tire). Sugbon nigbati won ba jade kuro lodo re apakan ninu won a pete ni oru yato si eyiti o so. Olohun si ko (sile) ohun ti won pa ni ete oru, nitorinaa seri lodo won, ki o si gbekele Olohun, Olohun si to ni Olugbekele. ※ Q4:81 surah An-Nisa
Posted on: Tue, 04 Mar 2014 10:10:36 +0000