Ti ojo ba ro gbogbo igi oko ati ile ma ngba itura ni. Aye re yio - TopicsExpress



          

Ti ojo ba ro gbogbo igi oko ati ile ma ngba itura ni. Aye re yio gba itura ayo, loni oluwa yio bu omi itura sinu aye re, sinu ise re. O so eso ayo, o se orire, wa lalubarika lagbara Edumare. Idawole idasele re gbogbo ni yio yori si rere. Amin When rain falls, trees and the soil are watered, they yield and bring forth abundant harvest. Today, God will water and nourish your life, you will prosper in all your endeavours. Your efforts shall bring fort exceeding blessings. Amen ~OA~♥
Posted on: Tue, 25 Jun 2013 08:44:02 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015