ctn/Ema wadi ohun ti ise itelorun fun Oluwa. E ma sin se ba ailere - TopicsExpress



          

ctn/Ema wadi ohun ti ise itelorun fun Oluwa. E ma sin se ba ailere ise okunkun kegbe po, sugbon e kuku maa ba won wi. Nitoripe itiju tile nin lati ma soro nkan wonni ti nwon nse nin ikoko". (DEUTRONOMY 4:27-29) "Oluwa yio sin tuyinka ninu awon orile ede, die nin eyin o si ku nin iye ninu awon orile ede, nibiti Oluwa Yio dari yin si. nibe nin eyin o si maa sin orisa ise owo enia, igi ati okuta tiko riran tiko sin gboran tiko jehun tiko sin gboorun. Sugbon bi iwo bawa Oluwa Olorun re lati ibe lo, iwo ori, bi iwo bafi gbogbo aiya re ati gbogbo okan re waA" (ISIAH 40:18-19) "Tani eyin o ha fi Olorun we (Jesus, Ogun, or Muhammad) Tani aworan kini enyin o fise akawe Re (Marry, Cross, Angel, Zhayeek, or Saint) onisonan ngbe ere, Alagbede wura sin nfi wura boo, osin da ewon fadaka" (KORINTIN KINI 10:19-21) "Nje kini emi nwi? pe orisa nin nkan tabi ohun ti afi rubo fun orisa nin nkan?
Posted on: Sat, 22 Jun 2013 07:53:43 +0000

Trending Topics



Recently Viewed Topics




© 2015